Proverbs 2:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
àwọn tí wọ́n ti kọ ọ̀nà òdodo sílẹ̀ tí wọn sì ń rìn ninu òkùnkùn;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹniti o fi ipa-ọ̀na iduroṣinṣin silẹ, lati rìn li ọ̀na òkunkun;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
tí ó kúrò ní ọ̀nà tààrà láti rìn ní ọ̀nà tí ó ṣókùnkùn,