Proverbs 2:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, máa rìn ní ọ̀nà àwọn eniyan rere, sì máa bá àwọn olódodo rìn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki iwọ ki o le ma rin li ọ̀na enia rere, ki iwọ ki o si pa ọ̀na awọn olododo mọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni ìwọ yóò rìn ní ọ̀nà àwọn ènìyàn rere kí o sì rìn ní ọ̀nà àwọn Olódodo