Proverbs 2:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà náà ni ìtumọ̀ òdodo ati ẹ̀tọ́ yóo yé ọ ati àìṣe ojuṣaaju, ati gbogbo ọ̀nà rere.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni iwọ o mọ̀ ododo, ati idajọ, ati aiṣegbe; ani, gbogbo ipa-ọ̀na rere.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni òye ohun tí ó tọ̀nà tí ó sì dára, tí ó dára yóò yẹ́ ọ—gbogbo ọ̀nà dídara.