Proverbs 21:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹni tí ó kọ etí dídi sí igbe talaka, òun náà yóo kígbe, ṣugbọn kò ní rí ẹni dá a lóhùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹnikẹni ti o ba di eti rẹ̀ si igbe olupọnju, ontikararẹ̀ yio ke pẹlu: ṣugbọn a kì yio gbọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹnikẹ́ni tí ó bá ti di etí rẹ̀ sí igbe olùpọ́njú, òun tìkárarẹ̀ yóò ké pẹ̀lú; ṣùgbọ́n a kì yóò gbọ́.