Proverbs 22:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
nítorí yóo dára tí o bá pa wọ́n mọ́ lọ́kàn rẹ, tí o sì ń fi wọ́n ṣe ọ̀rọ̀ sọ jáde.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ohun didùn ni bi iwọ ba pa wọn mọ́ ni inu rẹ; nigbati a si pese wọn tan li ète rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ohun dídùn ni bí ìwọ bá pa wọ́n mọ́ ní inú rẹ; nígbà tí a sì pèṣè wọn tán ní ètè rẹ.