Proverbs 22:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí OLUWA yóo gbèjà wọn, yóo fìyà jẹ àwọn tí wọn ń jẹ wọ́n níyà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori Oluwa yio gbija wọn, yio si gbà ọkàn awọn ti ngbà lọwọ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí OLÚWA yóò gbéjà wọn, yóò sì gba ọkàn àwọn tí ń gba tiwọn náà.