Proverbs 22:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Má bá wọn ṣe onígbọ̀wọ́ ẹni tó fẹ́ yá owó, má bá wọn ṣe onídùúró fún onígbèsè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Máṣe wà ninu awọn ti nṣe igbọwọ, tabi ninu awọn ti o duro fun gbèse.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Má ṣe wà nínú àwọn tí ń ṣe ìgbọ̀wọ́, tàbí nínú àwọn tí ó dúró fún gbèsè.