Proverbs 23:30 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí wọn máa ń pẹ́ ní ìdí ọtí ni, àwọn tí wọn ń mu ọtí àdàlú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti o duro pẹ nibi ọti-waini; awọn ti nlọ idan ọti-waini àdalu wò.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ó dúró pẹ́ níbi ọtí-wáìnì; àwọn tí ń lọ láti dán ọtí wáìnì àdàlú wò.