Proverbs 23:35 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
O óo wí pé, “Wọ́n lù mi, ṣugbọn kò dùn mí; wọ́n nà mí, ṣugbọn ń kò mọ̀. Nígbà wo ni n óo tó jí? N óo tún wá ọtí mìíràn mu.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ o si wipe, nwọn lù mi; kò dùn mi; nwọn lù mi, emi kò si mọ̀: nigbawo li emi o ji? emi o tun ma wá a kiri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ ó sì wí pé, “Wọ́n lù mí; kò dùn mí; wọ́n lù mí, èmi kò sì mọ̀: nígbàwo ni èmi ó jí? Èmi ó tún máa wá òmíràn láti mu.”