Proverbs 24:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọmọ mi, jẹ oyin, nítorí pé ó dùn, oyin tí a fún láti inú afárá a sì máa dùn lẹ́nu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọmọ mi, jẹ oyin, nitoriti o dara; ati afara oyin, ti o dùn li ẹnu rẹ:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ oyin, ìwọ ọmọ mi, nítorí tí ó dára, oyin láti inú afárá oyin dùn lẹ́nu.