Proverbs 24:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí pé bí olódodo bá ṣubú léra léra nígbà meje, yóo tún dìde, ṣugbọn àjálù máa ń bi ẹni ibi ṣubú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe olõtọ a ṣubu nigba meje, a si tun dide: ṣugbọn enia buburu yio ṣubu sinu ibi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí bí olódodo ènìyàn bá tilẹ̀ ṣubú ní ìgbà méje, yóò tún padà dìde ṣáá ni, ṣùgbọ́n ìdàámú yóò fa ènìyàn búburú lulẹ̀.