Proverbs 24:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọmọ mi, bẹ̀rù OLUWA ati ọba, má ṣe àìgbọràn sí ọ̀kankan ninu wọn;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọmọ mi, iwọ bẹ̀ru Oluwa ati ọba: ki iwọ ki o má si ṣe dàpọ mọ awọn ti nṣe ayidayida.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ̀rù OLÚWA àti ọba, ọmọ mi, má sì ṣe dara pọ̀ pẹ̀lú àwọn olórí kunkun