Proverbs 24:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
nítorí jamba lè ti ọ̀dọ̀ wọn wá lójijì, ta ló mọ irú ìparun, tí ó lè ti ọ̀dọ̀ àwọn mejeeji wá?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe wàhala wọn yio dide lojiji, ati iparun awọn mejeji, tali o mọ̀ ọ!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nítorí àwọn méjèèjì yóò rán ìparun òjijì sórí wọn, ta ni ó sì mọ irú ìyọnu tí wọ́n lè mú wá?