Proverbs 24:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọ̀rọ̀ ọlọ́gbọ́n tún nìwọ̀nyí: Kò dára láti máa ṣe ojuṣaaju ninu ìdájọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wọnyi pẹlu ni ọ̀rọ awọn ọlọgbọ́n. Kò dara lati ṣe ojuṣãju ni idajọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn wọ̀nyí pẹ̀lú tún jẹ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́gbọ́n láti ṣe ojúṣàájú níbi ìdájọ́ kò dára rárá: