Proverbs 25:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bí òtútù yìnyín nígbà ìkórè, bẹ́ẹ̀ ni olóòótọ́ iranṣẹ jẹ́, sí àwọn tí ó rán an, a máa fi ọkàn àwọn oluwa rẹ̀ balẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi otutu òjo-didì ni ìgba ikore, bẹ̃ni olõtọ ikọ̀ si awọn ti o rán a: nitoriti o tù awọn oluwa rẹ̀ ninu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí títutù òjò yìnyín ní àsíkò ìkórè ni ìránṣẹ́ tí ó jẹ́ olóòtọ́ sí àwọn tí ó rán an ó ń tu ọ̀gá rẹ̀ nínú.