Proverbs 25:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí òjò tí ó ṣú dudu tí ó fẹ́ atẹ́gùn títí ṣugbọn tí kò rọ̀, ni ẹni tí ó ń fọ́nnu láti fúnni lẹ́bùn, tí kò sì fúnni ní nǹkankan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹnikẹni ti o ba ṣefefe ninu ẹ̀bun ẹ̀tan, o dabi awọsanma ati afẹfẹ ti kò ni òjo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí ojú ṣíṣú àti afẹ́fẹ́ láì sí òjò ni ènìyàn tí ń yangàn nípa ẹ̀bùn tí kò fún ni.