Proverbs 25:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ògo ni ó jẹ́ fún Ọlọrun láti fi nǹkan pamọ́, ṣugbọn ògo ló sá tún jẹ́ fún ọba láti wádìí nǹkan ní àwárí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ogo Ọlọrun ni lati pa ọ̀ran mọ́: ṣugbọn ọlá awọn ọba ni lati wadi ọ̀ran.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ògo OLÚWA ní láti fi ọ̀rọ̀ kan pamọ́; láti rí ìdí ọ̀rọ̀ kan ni ògo àwọn ọba.