Proverbs 25:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mú àwọn olùdámọ̀ràn ibi kúrò lọ́dọ̀ ọba, a óo sì fi ìdí ìjọba rẹ̀ múlẹ̀ pẹlu òdodo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mu enia buburu kuro niwaju ọba, a o si fi idi itẹ́ rẹ̀ kalẹ ninu ododo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
mú ènìyàn búburú kúrò níwájú ọba a ó sì fìdí ìtẹ́ rẹ múlẹ̀ nípaṣẹ̀ òdodo.