Proverbs 25:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Má fi ìwàǹwára fa ẹnikẹ́ni lọ sílé ẹjọ́, nítorí kí ni o óo ṣe nígbà tí aládùúgbò rẹ bá dójútì ọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Máṣe jade lọ kankan lati jà, ki iwọ ki o má ba ṣe alaimọ̀ eyiti iwọ o ṣe li opin rẹ̀, nigbati aladugbo rẹ yio dojutì ọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ohun tí o ti fi ojú ara rẹ rí má ṣe kánjú gbé e lọ sílé ẹjọ́ nítorí kí ni ìwọ yóò ṣe ní ìgbẹ̀yìn bí aládùúgbò rẹ bá dójú tì ọ́?