Proverbs 29:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ohun tí ó sọ talaka ati aninilára di ọ̀kan náà ni pé, OLUWA ló fún àwọn mejeeji ní ojú láti ríran.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Talaka ati aninilara enia pejọ pọ̀: Oluwa li o ntan imọlẹ si oju awọn mejeji.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tálákà ènìyàn àti aninilára jọ ní àbùdá yìí, OLÚWA jẹ́ kí ojú àwọn méjèèjì máa ríran.