Proverbs 29:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọba tí ó dájọ́ ẹ̀tọ́ fún talaka, ní a óo fìdí ìjọba rẹ̀ múlẹ̀ títí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọba ti o fi otitọ ṣe idajọ talaka, itẹ́ rẹ̀ yio fi idi mulẹ lailai.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí ọba kan bá ń ṣe ìdájọ́ talákà pẹ̀lú òtítọ́ ìtẹ́ ìjọba rẹ yóò fìdí múlẹ̀ nígbà gbogbo.