Proverbs 29:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí eniyan burúkú bá wà lórí oyè, ẹ̀ṣẹ̀ a máa pọ̀ síi, ṣugbọn lójú olódodo ni wọn yóo ti ṣubú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati awọn enia buburu ba npọ̀ si i, irekọja a pọ̀ si i: ṣugbọn awọn olododo yio ri iṣubu wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ènìyàn búburú ń gbilẹ̀, bẹ́ẹ̀ náà ni ẹ̀ṣẹ̀ ń gbilẹ̀ ṣùgbọ́n Olódodo yóò rí ìṣubú wọn.