Proverbs 29:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọ̀rọ̀ ẹnu nìkan kò tó láti fi bá ẹrú wí, ó lè fi etí gbọ́ ṣugbọn kí ó má ṣe ohunkohun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A kì ifi ọ̀rọ kilọ fun ọmọ-ọdọ; bi o tilẹ ye e kì yio dahùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A kò le fi ọ̀rọ̀ lásán kìlọ̀ fún ìránṣẹ́ bí ó tilẹ̀ yé e, kò ní kọbi-ara-síi.