Proverbs 29:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí olódodo bá di eniyan pataki, àwọn eniyan a máa yọ̀, ṣugbọn nígbà tí eniyan burúkú bá wà lórí oyè, àwọn eniyan a máa kérora.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati awọn olododo wà lori oyè, awọn enia a yọ̀; ṣugbọn nigbati enia buburu ba gori oyè, awọn enia a kẹdùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí olódodo bá ń gbilẹ̀, àwọn ènìyàn a yọ̀ nígbà tí ènìyàn búburú ń ṣàkóso, àwọn ènìyàn ń kórìíra.