Proverbs 29:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Olódodo a máa bìkítà fún ẹ̀tọ́ àwọn talaka, ṣugbọn àwọn eniyan burúkú kò ní òye irú rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Olododo a ma rò ọ̀ran talaka: ṣugbọn enia buburu kò ṣú si i lati rò o.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Olódodo ń ṣaápọn nípa ìdájọ́ òtítọ́ fún àwọn tálákà, ṣùgbọ́n kò sí ohun tí ó kan ènìyàn búburú nínú irú rẹ̀.