Proverbs 30:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọ̀rọ̀ Aguri, ọmọ Jake ará Masa nìyí: Ọkunrin yìí sọ fún Itieli ati Ukali pé,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọ̀RỌ Aguri, ọmọ Jake, ọ̀rọ ẹkọ́ ti ọkunrin na ti sọ, fun Itieli, ani fun Itieli ati Ukali.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọ̀rọ̀ Ágúrì ọmọ Jákè, ọ̀rọ̀ ìṣọtẹ́lẹ̀ tí ọkùnrin yìí sọ fún Ítíélì, sí Ítíélì àti sí Úkálì: