Proverbs 30:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí wọ́n mọ́ lójú ara wọn, ṣugbọn a kò tíì wẹ èérí wọn nù.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iran kan wà, ti o mọ́ li oju ara rẹ̀, ṣugbọn a kò ti iwẹ̀ ẹ nù kuro ninu ẽri rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ó mọ́ ní ojú ara wọn ṣíbẹ̀ tí wọn kò sì mọ́ kúrò nínú èérí wọn;