Proverbs 30:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn kan wà tí ojú wọ́n ga, lókè lókè ni ojú wọn wà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iran kan wà, yẽ, oju rẹ̀ ti gbega to! ipenpeju rẹ̀ si gbé soke.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ẹni tí ojú wọn gbéga nígbà gbogbo, tí ìwolẹ̀ wọn sì kún fún ìgbéraga.