Proverbs 30:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn kan wà tí eyín wọn dàbí idà, kìkì ọ̀bẹ ló kún èrìgì wọn, láti jẹ àwọn talaka run lórí ilẹ̀ ayé, ati láti pa àwọn aláìní run láàrin àwọn eniyan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iran kan wà, ehin ẹniti o dabi idà, erigi rẹ̀ dabi ọbẹ, lati jẹ talaka run kuro lori ilẹ, ati awọn alaini kuro ninu awọn enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ẹni tí eyín wọn jẹ́ idà Àwọn tí èrìgì wọn kún fún ọ̀bẹ láti jẹ àwọn talákà run kúrò ní ilẹ̀ ayé àwọn aláìní kúrò láàrin àwọn ọmọ ènìyàn.