Proverbs 30:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Nítòótọ́ mo jẹ́ aláìmọ̀kan jùlọ ninu gbogbo eniyan, n kò ní òye tí ó yẹ kí eniyan ní.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitõtọ emi ṣiwère jù ẹlomiran lọ, emi kò si ni imoye enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Èmi ni aláìmòye ju nínú àwọn ènìyàn; N kò ní òye ènìyàn.