Proverbs 30:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
àwọn èèrà kò lágbára, ṣugbọn wọn a máa kó oúnjẹ wọn jọ ní ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Alailagbara enia li ẽra, ṣugbọn nwọn a pese onjẹ wọn silẹ ni ìgba ẹ̀run.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn èrà jẹ́ ẹ̀dá tí ó ní agbára díẹ̀ síbẹ̀ wọ́n kó oúnjẹ wọn pamọ́ ní àsìkò òjò