Proverbs 30:26 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ehoro ìgbẹ́ kò lágbára, sibẹsibẹ wọ́n ń kọ́ ilé sí pàlàpálá òkúta.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Alailagbara enia li ehoro, ṣugbọn nwọn a ṣe ìho wọn ni ibi palapala okuta.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ehoro jẹ́ ẹ̀dá tí kò ní agbára púpọ̀ ṣíbẹ̀ wọ́n ń ṣe ilé wọn sí ibi ihò àpáta;