Proverbs 30:29 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn nǹkan mélòó kan wà tí ìrìn yẹ, àwọn nǹkan pọ̀ tí ìrìn ẹsẹ̀ wọn máa ń wu eniyan:
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ohun mẹta ni mbẹ ti nrìn rere, nitõtọ, mẹrin li o dára pupọ ni ìrin rirìn:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Àwọn ohun mẹ́ta ní n bẹ tí ń rìn rere, ohun mẹ́rin tí ń kọrí sí ibi rere,