Proverbs 31:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kì í bẹ̀rù nítorí ìdílé rẹ̀ nígbà òtútù, nítorí gbogbo wọn ni ó ti bá hun aṣọ tí ó móoru.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On kò si bẹ̀ru òjo-didì fun awọn ara ile rẹ̀; nitoripe gbogbo awọn ara ile rẹ̀ li a wọ̀ li aṣọ iṣẹpo meji.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí òjò dídì rọ̀, kò bẹ̀rù nítorí ìdílé rẹ̀ nítorí gbogbo wọn ni ó wọ aṣọ tí ó nípọn.