Proverbs 31:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n dá ọkọ rẹ̀ mọ̀ lẹ́nu ibodè, nígbà tí ó bá jókòó pẹlu àwọn àgbààgbà ìlú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A mọ̀ ọkọ rẹ̀ li ẹnu-bode, nigbati o ba joko pẹlu awọn àgba ilẹ na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A bọ̀wọ̀ fún ọkọ rẹ̀ ní ẹnu ibòde ìlú níbi tí ó ń jókòó láàrin àwọn àgbà ìlú