Proverbs 31:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbọ́, ìwọ Lemueli, ọba kò gbọdọ̀ máa mu ọtí, àwọn aláṣẹ kò sì gbọdọ̀ máa wá ọtí líle.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kì iṣe fun awọn ọba, Lemueli, kì iṣe fun awọn ọba lati mu ọti-waini; bẹ̃ni kì iṣe fun awọn ọmọ alade lati fẹ ọti lile:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Kì í ṣe fún àwọn ọba, ìwọ Lémúélì kì í ṣe fún ọba láti mu ọtí wáìnì kì í ṣe fún alákòóso láti máa wá ọtí líle