Proverbs 31:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Fún ẹni tí ń ṣègbé lọ ní ọtí mu, fún àwọn tí ọkàn wọ́n bàjẹ́ ní ọtí líle,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Fi ọti lile fun ẹniti o mura tan lati ṣegbe, ati ọti-waini fun awọn oninu bibajẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fi ọtí líle fún àwọn tí ń ṣègbé wáìnì fún àwọn tí ó wà nínú ìrora;