Proverbs 4:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣọ́ra pẹlu èrò ọkàn rẹ, nítorí èrò ọkàn ni orísun ìyè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jù gbogbo ohun ipamọ́, pa aiya rẹ mọ́; nitoripe lati inu rẹ̀ wá ni orisun ìye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ju gbogbo nǹkan tó kù lọ, pa ọkàn rẹ mọ́ Nítorí òun ni oríṣun ìyè,