Proverbs 5:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Olólùfẹ́ rẹ tí ó dára bí abo egbin. Jẹ́ kí ẹwù rẹ̀ máa mú inú rẹ dùn nígbà gbogbo, kí ìfẹ́ rẹ̀ máa mú orí rẹ yá nígbàkúùgbà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi abo agbọnrin daradara ati abo igalà, jẹ ki ọmu rẹ̀ ki o ma fi ayọ̀ kún ọ nigbagbogbo; ki o si ma yọ̀ gidigidi ninu ifẹ rẹ̀ nigbakugba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Abo àgbọ̀nrín tó dára, ìgalà tí ó wu ni jọjọ Jẹ́ kí ọmú rẹ̀ tẹ́ ọ lọ́rùn nígbà gbogbo jẹ́ kí ìfẹ́ rẹ̀ máa fà ọ́ títí láéláé