Proverbs 5:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nisinsinyii, ẹ̀yin ọmọ mi, ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ mi, ẹ má sì kọ ọ̀rọ̀ sí mi lẹ́nu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Njẹ gbọ́ temi nisisiyi, ẹnyin ọmọ, ki ẹnyin ki o máṣe yà kuro li ọ̀rọ ẹnu mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, ẹ̀yin ọmọ tẹ́tí sí mi má ṣe yàgò kúrò nínú àwọn nǹkan tí mo sọ