Proverbs 6:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí fìtílà ni òfin, ìmọ́lẹ̀ ni ẹ̀kọ́, ìbáwí sì jẹ́ ọ̀nà ìyè,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe aṣẹ ni fitila; ofin si ni imọlẹ; ati ibawi ẹkọ́ li ọ̀na ìye:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí àwọn àṣẹ yìí jẹ́ àtùpà, ẹ̀kọ́ yìí jẹ́ ìmọ́lẹ̀, àti ìtọ́niṣọ́nà ti ìbáwí ni ọ̀nà sí ìyè