Proverbs 6:26 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Owó tí aṣẹ́wó yóo gbà kò ju owó burẹdi lọ, ṣugbọn gbogbo ẹ̀mí rẹ ni alágbèrè yóo fi ọgbọ́n gbà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe nipasẹ agbere obinrin li enia fi idi oniṣù-akara kan: ṣugbọn aya enia a ma wá iye rẹ̀ daradara.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nítorí Aṣẹ́wó yóò sọ ọ́ di àkàrà lásánlàsàn ẹ̀mí rẹ gan an sì ni alágbérè ń dọdẹ.