Proverbs 7:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, mo wá pàdé rẹ, mo fi ìlara wá ọ, mo sì rí ọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ni mo ṣe jade wá pade rẹ, lati ṣe afẹri oju rẹ, emi si ri ọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà ni mo ṣe jáde wá pádé è rẹ; mo wá ọ káàkiri mo sì ti rí ọ!