Proverbs 8:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí ibú omi tó wà ni mo ti wà, nígbà tí kò tíì sí àwọn orísun omi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati ọgbun kò si, a ti bi mi; nigbati kò si orisun ti o kún fun omi pipọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí kò tíì sí òkun, ni a ti bí mi nígbà tí kò tíì sí ìsun tí ó ní omi nínú;