Proverbs 8:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Ẹ̀yin eniyan ni mò ń pè, gbogbo ọmọ eniyan ni mò ń ké sí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹnyin enia li emi npè; ohùn mi si nkọ si awọn ọmọ enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sí i yín ẹ̀yin ènìyàn, ní mo ń kígbe pè; Mo gbé ohun mi sókè sí gbogbo ènìyàn,