Proverbs 8:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ tẹ́tí ẹ gbọ́, nítorí pé ọ̀rọ̀ pataki ni mo fẹ́ sọ. Ohun tí ó tọ́ ni n óo sì fi ẹnu mi sọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ gbọ́, nitori ti emi o sọ̀rọ ohun ti o dara, ati ṣiṣi ète mi yio sọ̀rọ ohun titọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tẹ́tí, nítorí mo ní àwọn ohun iyebíye láti sọ; Mo ya ẹnu mi láti sọ àwọn ohun tí ó tọ̀nà,