Proverbs 9:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó ti rán àwọn iranṣẹbinrin rẹ̀ kí wọn lọ máa kígbe lórí àwọn òkè láàrin ìlú pé:
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O ti ran awọn ọmọbinrin rẹ̀ jade, o nke lori ibi giga ilu, pe,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
ó ti rán àwọn ìránṣẹ́bìnrin rẹ̀ jáde, ó sì ń pè, láti ibi tí ó ga jù láàrin ìlú.