Psalms 10:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣẹ́ eniyan burúkú ati aṣebi lápá, tú àṣírí gbogbo ìwà burúkú rẹ̀, má sì jẹ́ kí ọ̀kan ninu wọn farasin.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣẹ́ apa enia buburu, ati ti ọkunrin ibi nì: iwọ wá ìwa-buburu rẹ̀ ri, titi iwọ kì yio fi ri i mọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣẹ́ apá àwọn ènìyàn búburú àti ènìyàn ibi; pèé láti wa sírò fún iwà ìkà Rẹ̀ tí a kò le è rí.