Psalms 10:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
kí o lè ṣe ẹ̀tọ́ fún àwọn aláìníbaba ati àwọn ẹni tí à ń pọ́n lójú, kí ọmọ eniyan, erùpẹ̀ lásánlàsàn, má lè dẹ́rù bani mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lati ṣe idajọ alaini-baba ati ẹni-inilara, ki ọkunrin aiye ki o máṣe daiya-fo-ni mọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti ṣe ìdájọ́ àwọn aláìni baba àti àwọn ti a ni lára, kí ọkùnrin, tí ó wà ní àyé, kí ó má ṣe dẹ́rùbà ni mọ́.