Psalms 10:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Pẹlu ìgbéraga ni eniyan burúkú fi ń dọdẹ àwọn aláìní; jẹ́ kí ó bọ́ sinu tàkúté tí ó fi àrékérekè dẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu igberaga li enia buburu nṣe inunibini si awọn talaka: ninu arekereke ti nwọn rò ni ki a ti mu wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú àrékérekè ènìyàn búburú ti ó gbérò ni kí a ti mú wọn, lí a mú-un nínú ìlànà tí o gbérò.